Revistas da Unilab (Univ. da Integração Internacional da Lusofonia Afro-Brasileira)
Not a member yet
    1125 research outputs found

    Ojúṣe èrò ìwòran nínú àgbéjádé lítíréṣọ̀ alohùn yorùbá: O papel da imaginação visual no desenvolvimento da literatura oral iorubá

    Full text link
    ÀṢAMỌ̀ Lítíréṣọ̀ alohùn ilẹ̀ Áfíríkà ti wà kí ètò ẹ̀kọ́ ilé-ìwé tó dé, èyí kò sì yọ àwọn Yorùbá ní Gúsù ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà sílẹ̀. Yorùbá ti ní wọ́n sì tún ní ohun tí a lè pè ní àṣà àti ìsẹ̀ṣe tí a mọ̀ wọ́n mọ̀. Èyí ni a lè pè ní lítíréṣọ̀ tiwọn èyí tí wọn ń tàn ká nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ ẹnu láti ìran kan sí èkejì tó sì kún ojú òṣùwọ̀n fún lílò láti rí i dájú pé àlàáfíà jọba láàrin wọn àti fún ìdàgbàsókè àwùjọ wọn. Ọ̀kan lára lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá ni ewì alohùn Yorùbá. Apilẹ̀kọ yìí ń ṣàgbéyẹ̀wò iṣẹ́ àwọn akéwì/apohùn, òṣèré, pàápàá jù lọ ipa èrò ìwòran lórí àgbéjáde lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá. Lára èròǹgbà iṣẹ́ àpilẹ̀kọ yìí ni: láti fi ojú lámèyítọ́ wo ipa àwọn èrò ìwòran nínú gbígbékalẹ̀ lítíréṣọ̀ alohùn; latí wo ànfààní tàbí àlébù ipa tí a ń wí yìí lórí oníṣẹ́ ọnà fúnrarẹ̀, èrò ìwòran àti àwùjọ lápapọ̀; A fi lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá ṣe ìtìsẹ̀ wa. Àwọn iṣé àpilẹ̀kọ díẹ̀ ti wà tí a lè tọ́ka sí lórí kókó ọ̀rọ̀ yìí. Lára wọn ni ti Àkàngbé (2021) àti Akínyẹmí (2012). Àwọn méjèèjì ló sọ̀rọ̀ léréfèé lóri ipa èrò ìwòran nínú àgbéjáde lítíréṣọ̀ àtẹnuwí. Àwọn wọ̀nyí ni a fi ṣe àtẹ̀gùn tí a sì wo orí ọ̀rọ̀ náà ní àwòfín. Aṣèwádìí ṣe àmúlò ọgbọ́n ìwádìí “ṣé kí n rí i” nípa síṣe alábápín ọdún egúngún ní ìlú kan ni ìpínlẹ̀ Kwara, kíkó àwọn ìpéẹ̀rẹ̀ jọ fún eré àlọ́, wíwo eré síṣe lọ́kan-ò-jòkan lórí ìtàgé àti nínú Sinnimọ́. Iṣẹ́ ìwádìí yìí sàmúlò tíọ́rì sosiọ́lọ́jì èyí tó ní ṣe pẹ̀lú ìbágbépọ̀ ara ẹni ní àwùjọ. A lo tíọ́rì yìí ní ìbámu pẹ̀lú ìgbàgbọ́ pé asàfihàn àwùjọ ní lítíréṣọ̀. Fún ìdí èyí, a ní èrò láti fihàn pé gbogbo ohun tí òṣèré, akéwì, apohùn ń gbé jádé ní ṣe pẹ̀lú àwùjọ. Àpilẹ̀kọ náà gúnlẹ̀ pé àwọn èrò ìwòran ní ipa pàtàkì láti kó nínú àgbéjáde lítíreṣọ̀ alohùn. Wọ́n ní ipa pàtàkì láti kó nínú àṣeyọrí tàbí ìkùnà akéwì, apohùn tàbí òṣèré. Ìdí nìyí tó fi ṣe pàtàkì láti fi wọ́n sí aàyè tó tọ́ sí wọn. Lára èròǹgbà iṣẹ́ ìwádí yìí ni láti jẹ́ kí a mọ̀ pé kìí ṣe wíwà ní ìkàlẹ̀ èrò ìwòran ló ṣe pàtàkì bí kò ṣe ipa wọn lóri àgbéjádé iṣẹ́ lítíréṣọ̀ alohùn. *****   A literatura oral africana existia antes do advento do sistema escolar, e isso não excluiu o povo iorubá do sudoeste da Nigéria. Os iorubás têm e ainda têm o que pode ser chamado de seus próprios costumes e práticas. Isso pode ser chamado de sua própria literatura, que eles espalharam por meio da transmissão oral de uma geração para outra e que é suficiente para garantir a paz entre eles e para o desenvolvimento de sua sociedade. Uma das formas de literatura oral iorubá é a poesia oral iorubá. Este artigo examina o trabalho de poetas/narradores, atores e, especialmente, a influência do teatro no desenvolvimento da literatura oral iorubá. Os objetivos deste artigo são: examinar criticamente o papel dos conceitos visuais no desenvolvimento da literatura oral; examinar os benefícios ou desvantagens dessa influência sobre o próprio artista, o conceito visual e a sociedade como um todo; e usar a literatura oral iorubá como ponto de partida. Existem alguns artigos que podem ser citados sobre este tema. Entre eles estão os de Ákangbé (2021) e Akínyêmí (2012). Ambos discutiram brevemente o papel dos conceitos visuais no desenvolvimento da literatura oral. Estes são usados como um trampolim e analisamos o tópico sob uma perspectiva. O pesquisador utilizou o método de pesquisa "deixe-me ver" participando de uma comunidade de 10 anos em uma cidade no estado de Kwara, coletando amostras para uma peça e observando apresentações no palco e no cinema. Este trabalho de pesquisa utilizou a teoria sociológica, que trata da interação social dos indivíduos em sociedade. Essa teoria foi utilizada de acordo com a crença de que a sociedade é um reflexo da literatura. Portanto, pretendemos mostrar que tudo o que um ator, poeta ou escritor produz está relacionado à sociedade. O artigo conclui que as ideias do público desempenham um papel significativo na produção de obras literárias. Elas desempenham um papel significativo no sucesso ou fracasso de um poeta, escritor ou ator. Por isso, é importante dar a elas o devido lugar. Parte do propósito desta pesquisa é nos fazer perceber que não é a presença de ideias visuais que importa, mas sim o seu papel no desenvolvimento de obras literárias

    Ìtúpalè̩ Ìs̩àfihàn Èrò Ìjìnlè̩ nípa Agbára Olódùmarè, Ìsò̩rí Ìs̩è̩dá Abè̩mí, àti Aje̩mé̩ranko nínú Ìlò Oríkì: A Socio-Cultural Analysis of Power of Creator, Creatures, and Animatory Creatures through the use of Oríkì

    Full text link
    ÀS̩AMÒ̩ Onírúúrú àkíyèsí ni ó ti wà s̩aájú is̩é̩ ìwádìí yìí tí ó fi hàn pé, ìran Yorùbá jé̩ ìran kan tí wó̩n kún fún àkíyèsí, àti àròjinlè̩ nípa àyíká wo̩n. Bákan náà ni pé, ìran Yorùbá kún fún àròjinlè̩ nípa ìgbésí ayé tí wo̩n ń gbé. Àìdé̩ye̩ sí ìgbàgbó̩ nínú èrò ìjìnlè̩ wo̩n pé Olódùmarè ni orí fún gbogbo ìs̩è̩dá, yálà abè̩mí, tàbí aláìlé̩mìí jé̩ ohun tí wó̩n máa ń fi hàn níbikíbi ti wó̩n bá ti ní ànfààní. Ní pàtàkì, wó̩n ń s̩e àfihàn àwo̩n nǹkan ìs̩è̩dá o̩wó̩ Olódùmarè nínú ìlò oríkì tí wó̩n máa ń s̩è̩dá. Èyí hàn gbangba nínú oríkì tí wó̩n ń hun fún àwo̩n ohun ìsò̩rí abè̩mí aje̩mé̩ranko tí wó̩n gbà pé Olódùmarè dá, tí ènìyàn ń sìn, èyí tí wo̩n kì í sìn, àti àwo̩n è̩dá inú omi. Nítorí náà, nínú is̩é̩ ìwádìí yìí, a tó̩ka sí aagbo̩n ìs̩àmúlò oríkì gé̩gé̩ bí abala kan pàtàkì tí Yorùbá fi ń fi àròjinlè̩ wo̩n hàn nípa nǹkan àyíká wo̩n, tí ó je̩ mó̩ ìs̩e, ìhùwàsí àti àkíyèsí wo̩n, nípa àwo̩n ìsò̩rí ìs̩è̩dá abè̩mí àti àwo̩n ìs̩è̩dá aje̩mé̩ranko àyíká wo̩n. Ìlànà ìwádìí tí a lò ni s̩ís̩e àkójo̩ àwo̩n àròfò̩, oríkì àti orin àwo̩n apohùn fún àwota. A s̩e àgbéyè̩wò àkóónú ìpèdè oríkì tí ó gbajú-gbajà tí àwo̩n apohùn hun jo̩, fún àfihàn àwo̩n ìje̩lógún èrò is̩é̩ yìí. A s̩e àgbéyè̩wò ò̩pò̩lo̩pò̩ àwo̩n oríkì tí ó wà lórí àwo̩n ìsò̩rí ìs̩è̩dá abè̩mí tí a s̩à yàn fún àlàyé kíkún. Tíó̩rì Ìfojú-Às̩à-Ìbílè̩-wo is̩é̩-o̩nà lítírésò̩ ni a fi s̩e àwòta fún ìtúpalè̩ láti fi hàn pé, èrò àròjinlè̩ nípa ìs̩esí, ìhùwàsí àti ìrísí àwo̩n ìs̩è̩dá abè̩mí tí a tó̩ka sí nínu is̩é̩ yìí, ni ó bí ìlànà ìhun oríkì tí ìran Yorùbá s̩e àgbékalè̩ rè̩. Is̩é̩ yìí túnbò̩ fi òye kíkún hàn nípa bí ìgbàgbó̩ ìran Yorùbá s̩e lóòrìn tó, nípa ìpèdè “As̩è̩dá, Olúdá ayé àti ò̩run, àti “Olùdá ohun gbogbo” tí àwo̩n onímò̩ kan ti fún Olódùmarè. è̩wè̩, a se àfihàn bí ìran Yorùbá s̩e ní ìgbàgbó̩ púpò̩ nínú agbára Olódùmarè, Ìyà mi, àjo̩s̩epò̩, àti ojús̩e àwo̩n nǹkan abè̩mí sí ara won nínú ìpèdè oríkì tí a se ìtúpalè̩ nínú is̩é̩ àpilè̩ko̩ yìí láti fi ìdí èrò múlè pé, ìsesí, ìhùwàsí àti àwo̩n àbùdá è̩dá kò̩ò̩kan ni ó ń ran alátinúdá ló̩wó̩ fún ìhun oríkì tí wó̩n ń hun.  ***** Houve várias observações antes desta pesquisa que mostram que o povo iorubá é um povo repleto de observações e imaginação sobre seu ambiente. Da mesma forma, o povo iorubá é repleto de imaginação sobre a vida que leva. A crença profunda de que Deus é a cabeça de toda a criação, seja animada ou inanimada, é algo que demonstram sempre que têm oportunidade. Em particular, demonstram as criações de Deus por meio da poesia que criam. Isso é evidente na poesia que compõem para as criaturas que acreditam ter sido criadas por Deus, aquelas que adoram, aquelas que não adoram e as criaturas aquáticas. Portanto, nesta pesquisa, nos referimos ao uso da poesia como um aspecto importante da maneira iorubá de expressar seus pensamentos sobre seu ambiente, ou seja, suas ações, comportamentos e observações sobre as criaturas da natureza e as criaturas de seu ambiente. O método de pesquisa utilizado foi coletar poemas, canções e cânticos dos poetas para o propósito do estudo. O conteúdo dos poemas mais populares escritos pelos poetas foi analisado para demonstrar os dez princípios deste estudo. Diversos poemas sobre o tema da criação da alma foram analisados e selecionados para uma análise detalhada. A teoria da perspectiva nativa americana sobre obras literárias é utilizada como estrutura para o estudo, a fim de demonstrar que a profunda compreensão das ações, comportamentos e aparência das criaturas mencionadas nesta obra deu origem aos princípios poéticos sobre os quais o povo iorubá se baseou. Este trabalho também demonstra uma compreensão completa do quanto o povo iorubá acredita na poesia, por meio da linguagem de "As̩è̩da", "Oludu aya at ô̩rún" e "Oludu ohun gbogbo", que alguns estudiosos atribuíram a Olódùmarè. Neste trabalho, demonstramos o quanto o povo iorubá acredita no poder de Olódùmarè, Iyà mi, àjo̩epo̩ e nas responsabilidades dos seres vivos uns para com os outros, na linguagem poética apresentada neste artigo, para estabelecer a ideia de que as ações, os comportamentos e as características de cada criatura são o que os poetas usam para tecer a poesia que tecem. &nbsp

    Ìṣàfihàn onírúurú ọ̀nà ìjóbìnrin nínú àṣàyàn iṣẹ́ ọnà aláwòmọ́ lítíréṣọ̀ Yorùbá: Representations of women dynamism in selected Yorùbá literary genres

    Full text link
    ÀṢAMỌ̀ Ìmọ̀ nípa ìbáṣepọ̀ tó wa láàrin takọ-tabo ti gbọ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ láàrin àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ lẹ́lẹ́kajẹ̀ka. Obìnrin àti ipò wọn gẹ́gẹ́ bí àṣà àti ìṣe ti fi lọ́lẹ̀ sì jẹ wọ́n lógún. Àwọn onímọ̀ kan gbà pé àṣà àwùjọ Yorùbá n gbé èrò akọ-lo-lórí lẹ́yìn àmọ́ ọ̀pọ̀ ìwádìí lo tún ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ipò àti ipa pàtàkì ni obìnrin ti kó, tí wọ́n sì tún ń kó láwùjọ Yorùbá. Àfojúsùn iṣẹ́  yìí ni ṣíṣe àyẹ̀wò ipò àti ipa tí obìnrin ń kó nínú ètò àti ẹ̀tọ́ ìlú bí ó ti hàn nínú àṣàyàn lítíréṣọ̀ Yorùbá. Tíọ́rì Ìṣẹ̀tófábo ti Clenora Hudson-Weems ni a gùnlé láti ṣàtúpalẹ̀ àṣàyàn oríkì orílẹ̀, eré-onítàn àti fíìmù Yorùbá tí a mọ̀-ọ́n-mọ̀ yàn láàyò nítorí àkóónú wọn. Àwọn iṣẹ́ ọnà aláwòmọ́ lítíréṣọ̀ náà ni: Akínwùmí Ìṣọ̀lá, Ẹfúnṣetán Aníwúrà, Olú-Ọmọ, Ẹfúnróyè Tinúubú; Oríkì Arẹ̀sà bí ó ti hàn nínú Adébóyè Babalọlá Àwọn Oríkì orílẹ̀ Mẹ́tàdínlógún; àti fíìmù àgbéléwò Fúnmiláyọ̀ Ransome Kútì tí Túndé Babalọlá kọ.  Iṣẹ́ yìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ipa pàtàkì ni àwọn obìnrin ti ń kó láwùjọ Yorùbá láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìtàn ṣe fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀. Bákan náà ó hàn pe ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ní àwọn obìnrin kan. Síwájú sí, ipa tí obìnrin ń kó nínú ètò àti ẹ̀tọ́ ìlú ní ayé àtijọ́ títí di òní kò ṣe é fọbẹ̀ bù dànù. Bákan náà ni iṣẹ́ yìí fi hàn wí pé láti ayébáyé ni àyè ti gba obìnrin ní àwùjọ Yorùbá. Iṣẹ́ yìí tún fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé lítíréṣọ̀ Yorùbá jẹ́ ohun èlò láti fi ìjóbìnrin lọ́lẹ̀ láwùjọ. Ó sì tún fi hàn pé a le lò ó láti fi èrò báyéserí ẹni múlẹ̀. ****** Studies on gender discourse in African society has been privileged by scholars in almost all discipline. Existing studies in Yorùbá have focused largely on the cultural tradition and role of women. Generally, the Yorùbá people are assumed to be culturally patrilineal with women often subjugated and marginalized. This study, therefore, using Clenora Hudson-Weems African Womanism approach, this paper was designed to examine the dynamism of Yorùbá women as represented in selected Yorùbá literary genres, with a view to establishing the place of women in human, social and national development. The interpretive design was used to examine one Oríkì orílẹ̀, three plays and a home video purposively selected due to their thematic relevance. They are Akínwùmí Ìṣọ̀lá’s Ẹfúnsetán Aníwúra, Olú Ọmọ and Ẹfúnróyè Tinúubú; Oríkì Arẹ̀sà as documented in Adébóyè Babalọlá’s Àwọn Oríkì Mẹ́tàdínlógún and Túndé Babalọlá’s Fúnmiláyọ̀ Ransome Kútì. The texts were subjected to literary analysis. The study reveals that women occupy a significant space in both the pre-literate and contemporary era, with some women emerging as human rights activists and advocates. The paper establishes that Yorùbá literary genres have been used as weapons to negotiate spaces for women, and also as a tool used to herald the voice of women both in the pre-colonial and contemporary Yorùbá society and by extension, the larger Nigerian society

    Ìdálùú Nìṣèlú: Láríjà Àkóónú Ọdún Ìbílẹ̀ Ọ̀pá ní Ìlú Osí àti Ìlú Ìpinṣà: Controvérsia política: o conteúdo do Ano Tradicional do Cachorro nas cidades de Osi e Ipinsha

    Full text link
    ÀṢAMỌ̀ Ìwádìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ọdún Ọ̀pá gbéra sọ ní ìlú Osí tí ó wà ní ìhà àríwá Àkúrẹ́ ní ọdún 1419, kò sẹ́ni tó lè fi ìdí déètì pàtó tí ọdún náà bẹ̀rẹ̀ múlẹ̀. Orúkọ akọnikùnrin tí wọ́n ń fi ọdún Ọ̀pá bọlá fún ní ìlú Osí ni Akinlúùsẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ ọ́n sí Òrìṣà-Akin. Akọnibìnrin ni àwọn ará Ìpinṣà tí wọ́n ń gbé ní ìhà Gúsù Àkúrẹ́ ń bọlá fún ní tiwọn, orúkọ rẹ̀ ni Èyé-Mọ̀é. Àwọn akọni wọ̀nyí ni àwùjọ méjèèjì sọ di òrìṣà àkúnlẹ̀bọ nítorí ipa mánigbàgbé tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn kó ní àwùjọ rẹ̀. Ẹgbàágbèje iṣẹ́ ni àwọn onímọ̀ ti ṣe lórí onírúurú ọdún ìbílẹ̀ Yorùbá, ṣùgbọ́n iṣẹ́ kò tíì dunlẹ̀ lórí ìjọra àti ìyàtọ̀ tó hànde nípa àwọn ìgbésẹ̀, tó fi mọ́ ìpohùn tó ń wáyé nígbà tí wọ́n bá ń ṣe ọdún Ọ̀pá ní Osí àti Ìpinṣà. Pẹ̀lú àmúlò tíọ́rì Ìfojú-àṣà-ìbílẹ̀-wò, iṣẹ́ yìí gùn lé ọ̀rínkínniwín ìtọpinpin nípa àwọn ìlànà à-ń-tẹ̀lé tó forímù sínú ọdún kọ̀ọ̀kan, ó ṣe àyẹ̀wò láríjà onírúurú ìgbòkègbodò tó rọ̀ mọ́ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn, pàápàá jù lọ, ìtọ́ka sí ohun tí ó wọ̀ ní ìlú kan gẹ́gẹ́ bí ohun tí kò wọ̀ ní ìlú kejì, ó sì jíròrò lórí àwọn àkóónú tó pa ọdún méjèèjì pọ̀ àti àwọn tó yà wọ́n sọ́tọ̀. Ọgbọ́n ìṣèwádìí tí a gùnlé ni pé, a kópa nínú ọdún náà, a sì gba détà nípasẹ̀ ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò. Orí èrò tí ìwádìí yìí gúnlẹ̀ sí ni pé bí ìlú méjì bá bá ara wọn tan, tí wọ́n bá sì ń ṣe ọdún tó ń jẹ́ orúkọ kan náà ní oṣù kan náà lọ́dọọdún, síbẹ̀ èrò ìran Yorùbá tó sọ pé, ‘báyìí là ń ṣe nílẹ̀ yìí, èèwọ̀ ni ní ilẹ̀ ibòmíràn,’ kò níí ṣàìfẹsẹ̀múlẹ̀ ṣinṣin sínú ìgbòkègbodò ọdún tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ń ṣe. ***** Pesquisas estabeleceram que o ano de Opa começou na cidade de Osi, localizada ao norte de Akure, no ano de 1419, embora ninguém possa confirmar a data exata de seu início. O nome do herói homenageado com o ano de Opa na cidade de Osi é Akinlùùssè, conhecido por muitos como Orììa-Akin. O povo Ipinsha, que vive ao sul de Akure, homenageia uma heroína, cujo nome é Èyé-Mòé. Esses heróis foram transformados em divindades por ambos os grupos devido ao papel inesquecível que cada um deles desempenhou em sua comunidade. Estudiosos têm trabalhado extensivamente sobre os vários festivais tradicionais iorubás, mas pouco se tem feito sobre as semelhanças e diferenças que emergem dos rituais, incluindo os rituais que ocorrem durante a celebração do festival de Opa em Osi e Ipinsha. Utilizando a teoria da perspectiva cultural, este trabalho amplia o escopo do estudo dos rituais que moldam cada festival, examina a interação das diversas atividades associadas a cada um e, em particular, discute as semelhanças e diferenças entre os dois festivais. A metodologia de pesquisa utilizada foi a participação no ano e a coleta de dados por meio de entrevistas. A premissa desta pesquisa é que, se duas cidades estão relacionadas e celebram um ano com o mesmo nome no mesmo mês todos os anos, a crença iorubá de que "é assim que fazemos nest

    Eriendo rẹ Ọtaphia: Efuẹrẹ rẹ ekuakue rẹ Uhworo vwẹ ona rẹ Ọtaphia: Rhythms of Expression: Exploring Urhobo Musical Instruments in Verbal Arts

    Full text link
    Uyono nana fuẹrẹn ọsoso rẹ iruo rẹ ekuakua uhivoro rẹ uhworo ruẹ vwẹ ona rẹ ọtaphia, obo rẹ orukugbe rayen epha vwẹ ine rẹ Urhobo. A nabọ fuẹrẹ ekuakua rẹ uhworo kerẹ: ozi, agba, agogo, akaba, iwisoro, ẹshẹshẹghẹ, igede otete, Igbede ode, agidigbo, egbagben, iwisoro, ibani kugbe ogban, kerẹ ekuakua rẹ vwo dje kpahe irueru rẹ akpoeyere, obori fori, dje odavwe, iroroevun, ovuẹ, kugbe ọmrevughe rẹ orho phia. A reyọ ona rẹ ẹfuẹrẹ rẹ ẹtimografiki vẹ oruphia vwo dje obo rẹ ẹkuakua uhworo rẹ Urhobo vwẹ ukecha vwọ kẹ ukokodo rẹ ikuegbe vẹ oruru ẹkparọ, rọ ghwa orukugbe cha, rọ dia oka rẹ irueru ri shephiyọ vẹ uyovwin eta ri shekpahẹ irueru awanre, etavwerhe re kpare ẹwẹn kugbe, kpahe irueru awanre, etavwerhe re kparẹ ẹwẹn kugbe ineroro, vwọ vue ovuẹ roshephiyọ kẹ ihwo rẹ ekuotọ na. Ẹfuẹrẹ nana toro ba ẹruọ vẹ ọmrẹvughe rẹ irueru rẹ uhworo rẹ Afrika kugbe obo rẹ irueru uhworo vẹ ona re ẹtaphia wian kugbe, ro dje ọmrẹvughe rẹ erhuvwu rẹ ekuruemu rẹ Urhobo nẹ awanre rhe phia. **** This study examines the integral role of traditional Urhobo musical instruments in verbal arts, highlighting their symbiotic importance in traditional songs. Musical instruments such as ozi, agba, agogo, akaba, eshẹshẹghẹ, igede otete, igede ode, agidigbo, egbagen, iwisoro, ibani and ọgban are analyzed as vessels of cultural expression, conveying emotions, values, messages, and community identity. Through ethnographic research and performance analysis, this research reveals how Urhobo musical instruments enhance narrative depth and emotional resonance, facilitate communal participation and engagement, symbolize cultural values and mythological themes, inspire creative expression and improvisation and pass the right messages to citizens. This research contributes to the understanding of African musical traditions and their intersection with verbal arts, underscoring the significance of Urhobo cultural heritage in contemporary artistic expressions

    AS EXPERIÊNCIAS MIGRATÓRIAS PARA ÁFRICA DO SUL:: DO PASSADO AO PRESENTE E O SURGIMENTO DE NOVOS FENÓMENOS SOCIAIS

    Full text link
    Ao estudar as experiências migratórias para a África do Sul, o presente artigo mostra como é que os cidadãos dos territórios vizinhos da África do Sul responderam às oportunidades de emprego existentes ao longo do tempo desde o período da economia agrária, economia mineira e, no período depois de 1994, continuaram em busca de oportunidades, por meio da emigração ilegal, cujas consequências são descritas ao longo do presente texto. O artigo pretende contribuir para o estudo dos novos fenómenos sociais e económicos relacionados com as migrações na África austral, mostrando que, apesar de ser um processo antigo, envolvendo povos de toda a região, actualmente está acompanhado de certos males sociais que foram pouco abordados por muitos estudiosos da matéria para a sua elaboração. Nesse estudo, houve recurso ao método bibliográfico e à história de vida

    PRÁXIS PSICOSSOCIAL DE SUPERAÇÃO DO TRAUMA NO MASSACRE DE FELISBURGO

    Full text link
    Este artigo aborda os aspectos teórico-metodológicos da pesquisa-intervenção realizada no acampamento Terra Prometida, localizado na cidade de Felisburgo (MG), onde ocorreu um massacre contra trabalhadores rurais sem-terra, no ano de 2004, que ficou conhecido como o Massacre de Felisburgo. Considerada uma práxis interventiva, teve como objetivo principal buscar subsídios no sentido de produzir uma terapêutica comunitária em casos de violência extrema e trauma psicossocial. Fundamenta-se nos postulados da Psicologia da Libertação, da Psicologia Sócio-Histórica e apresenta-se uma contribuição específica da práxis formulada no decorrer da intervenção, que diz respeito à utilização da memória histórica (Martín-Baró) e da teoria dos afetos políticos (Sawaia). Assim, descrevemos e dialogamos sobre os pressupostos da Psicologia da Libertação e da Psicologia Sócio-Histórica; relatamos nossa participação na construção de uma Psicologia voltada para a questão da terra e dos povos do campo; e apresentamos uma contribuição específica da práxis formulada no decorrer da intervenção, que diz respeito à utilização da memória histórica e da teoria dos afetos políticos. Além disso, fica demonstrada a possibilidade de a Psicologia Social atuar nos níveis micro, meso e macrossociais. Para tanto, apresentamos um relato das intervenções e finalizamos com uma análise da avaliação dos sujeitos participantes em relação à pesquisa. &nbsp

    DEZ ANOS DE AÇÕES DE EXTENSÃO DO GRUPO DIÁLOGOS: QUESTÕES TEÓRICO-EMPÍRICAS

    Full text link
    In this work, we present and analyze extension actions developed by an extension and research group linked to the University of International Integration of Afro-Brazilian Lusophony (UNILAB). The central problem investigated involves understanding the characteristics, place, role, relevance and results of academic extension, considering ten projects executed between 2015 and 2025. The methodology involved participant observation and the analysis of documents and scientific production, in dialogue with theoretical-empirical vectors structuring extension at the University and in the country in recent decades. As main results, we characterized and discussed actions carried out by UNILAB extension workers and external partners, dialoguing with vectors such as the inseparability between teaching, extension and research; the dialogical, constructive and transformative interaction involving academic and non-academic agents; the production of changes in the institution itself and in society, involving the construction and operation of knowledge; the involvement of students, promoting their citizenship education; support in ethical principles that express the social commitment of higher education institutions; participation in the production and construction of knowledge, aimed at generating alternatives to development. The conclusions point to the centrality of engaged extension, inseparability and dialogicity in the Group\u27s extension experience, articulating social experiences, scientific and popular-community agents and knowledge and transformative practices, and evidencing the importance of academic extension actions developed by UNILAB agents and external partners.Neste trabalho, apresentamos e analisamos ações de extensão desenvolvidas por um grupo de extensão e pesquisa vinculado à Universidade da Integração Internacional da Lusofonia Afro-Brasileira (UNILAB). O problema central investigado envolve o entendimento das características, lugar, papel, relevância e resultados da extensão acadêmica, considerando dez projetos executados entre 2015 e 2025. A metodologia envolveu a observação participante e a análise de documentos e produção científica, em diálogo com vetores teórico-empíricos estruturantes à extensão na universidade e no país nas últimas décadas. Como principais resultados, caracterizamos e discutimos ações efetivadas por extensionistas da UNILAB e parceiros externos, dialogando com vetores como a indissociabilidade entre ensino, extensão e pesquisa; a interação dialógica, construtiva e transformadora envolvendo agentes acadêmicos e não acadêmicos; a produção de mudanças na própria instituição e na sociedade, envolvendo construção e operação de conhecimentos; o envolvimento de discentes, promovendo a sua formação cidadã; o apoio em princípios éticos que expressem o compromisso social das instituições de educação superior; e a participação na produção e na construção de conhecimentos, voltados à geração de alternativas ao desenvolvimento. As conclusões apontam para a centralidade da extensão engajada, da indissociabilidade e da dialogicidade na experiência de extensão do grupo, articulando experiências sociais, agentes e conhecimentos científicos e popular-comunitários e práticas transformadoras, e evidenciando a importância das ações de extensão acadêmica desenvolvidas por agentes da UNILAB e parceiros externos

    A normação do ensino Superior em Moçambique, perspetivas e desafios para as Unidades Orgânicas na província do Niassa: Um estudo de caso

    Full text link
    Abstract: This article is the result of theoretical, documentary research, presenting a perspective on some standards that regulate higher education in Mozambique, a nation located in Southern Africa. The standards based on Decree 43/2023 of August 2nd and Decree 91/2023 of December 29th, aim to strengthen inspection and quality assurance mechanisms. The choice of the theme is a concern for the author, regarding the study of the path of higher education institutions in the province of Niassa. Observe the parts of the instruments, as challenges for the Organic Units existing in the province. The reforms brought, if observed, on the one hand will be beneficial for the development of the higher education subsystem and on the other hand, the reforms will force higher education institutions to discontinue some course or program due to lack of requirements. Still from the author\u27s perspective, the requirements formulated aim to bring credibility to universities with regard to their principles that they value in teaching, research, extension, technological incubation, internationalization and other standards for their consolidation. The specific objectives aim to verify the existence of all normative elements for the full functioning of the organic units of the HEI existing in the province of Niassa. In this context, the reforms are expected to accelerate the quality of teaching in existing higher education institutions in the Province of Niassa. Inspection must serve as a means of preventing risks, and expected sanctions serve as a basis for stopping the operation of higher education institutions that commit irregularities. The inspection must apply the Law, as it is judged to be ineffective in sanctioning institutions that violate the Law. Keywords: Decree, normalization, higher education, reforms and challenges, perspectives for Niassa.Resumo: O presente artigo é decorrente de uma pesquisa do cunho teórico, documental, apresentando uma perspectiva sobre algumas normas que regulam o ensino superior em Moçambique, nação situada na Africa Austral. As normas assentes no Decreto 43/2023 de2 de Agosto e Decreto 91/2023 de 29 de Dezembro, visam fortalecer os mecanismos de fiscalização e garantia de qualidade. A escolha do tema constitui preocupação no autor, no que toca ao estudo sobre o percurso das instituições de ensino superior na província de Niassa. Observar as partes dos instrumentos, como desafios para as Unidades Orgânicas existentes na província. As reformas trazidas, se observadas, por um lado serão benéficas para o desenvolvimento do subsistemado ensino superior e por outro lado, asreformas irão obrigar as instituições de ensino superior adescontinuar algum curso ou programa por falta de requisitos. Ainda na óptica do autor, as exigências formuladas visam trazer credibilidade das universidades no que diz respeito aos seus princípios que prezam sobre o ensino, pesquiza, extensão, incubação tecnológica, internacionalização e outros padrões para sua consolidação. O artigo tem como objectivo geral: Verificar a conformidade do funcionamento da instituição com base nas normas vigentes. Os objectivos específicos visam verificara existência de todos elementosnormativos para o funcionamento pleno das unidades orgânicas da IES existente na província de Niassa. Neste contesto, se espera diante das reformas acelerar a qualidade de ensinonas instituições de ensino superior existentes na Província de Niassa. A fiscalização deve servir como um meio de prevenção de riscos, e sanções prevista sirvam como fundamento para parar com o funcionamento de instituições de ensino superior que, cometem irregularidades. A inspecção deve aplicar a Lei, pós se julga ser inoperante em sancionar as instituições infratoras da Lei. Palavras-chave: Decreto,normalização, ensino superior, reformas e desafios, perspectivas para Niassa.     Ciwunganyo: Aci cibuukuci cikuteenda upaande um usoomi  wa n’ciganicisyo, yibuuku, n’kusaala ya kuloleela midingo jiine jaakwe já jikuloleela n’nyikoola yeekuluungwa m’Mosambiki, cilaambo ca cidi kwivaanda kwa n’cigoombo ca África. Midingo já jidi um ulamusi 43/2023 wa 2 mweesi wa Agostu ni ulamusi 91/2023 wa 29 wa mweesi wa Deseemba, wu kupeleka matala ga  ulonda pa kusaka cipatikane citupyo. Kusagula kwa awu n’tengaawu wu kuoneka yisawusyo ya va kuleembava, pa kujaaga matala ga ga-kujigala yikoola yeekuluungwa  n’cigoombo ca ku-Nyassa. Kuloleela n’tupaande, m’pela yidimbi-dimbi n’nyijiiji kapena yikoola yeekuluungwa ya yidi ku-Niassa. Ya yicenjileeyo, naaga kuyilolecesya, m’paka yipelece cikamucisyo n’nyikoola yeekuluungwa, naambo paane paakwe, ci yiteendekaasye kuva laasima yikoola yeekulungwa yine yakwe yikajeendelecela kuluso sine syaakwe digoongo dya kusova yisuuso. Pa kulola kwa va kuleembaava, malamusi ga nyuuwaniga gakusaka kujigadila cikulupi n’nyikoola yeekuluungwayi pakujaaga m’myaambo já jikuloleela m’masoomo-mo, kusosa-sosa,cituuwo, ku wukamicisya m’ma Tekenolojia, kutaandicila m’paka yilaambo yiine ni yipiimo yine yakwe pakuti yikamulane. Aci cibuukuci cikweete cidiimbi- cekuluungwa: Kupima ya yikuti kuseveesa yikoola yeekuluungwayo pa kukuuya midingo. Yidimbi-dimbi yamwana ni yidi ya kuloleela anaaga  yipadi yoose ya yikusacikwa pakuti yikoola yeekuluungwa yiveeje ya kuseveesa mwa n’tendeele ku-Nyassa. Pelepo, yikudindidwa kwa yiciimdu ya yikudindidwa kwa yiciimdo ya yicenjileeyo, kuutusya wusoomi wambone wa yikusacikwa n’nyikoola yeekuluungwa ku-Nyassa. Ulonda uveeje wa kusosegwa pa kuyikaanya yiciindu yakana maate, ni, ukayidi uveeje wa kusosegwa pa kuyiciga yikoola yeekuluungwa ya yikuleka kukuuya midingo. N’kutula wa ulonda uveeje wa kupikunicisya ulamusi, n’taande yikupiikanika kuti ukuteenda uleesi pa kupeleka ukayidi n’nyituwo ya ngayikuuya  ulamusi. Aluvu sya kuwidisya-widisya: Ulamusi, midingo, yikoola, yeekuluunwa, ya kuloleela, yidimbi-dimbi pakujaaga ku-NyaasaO presente artigo é decorrente de uma pesquisa do cunho teórico, documental, apresentando uma perspectiva sobre algumas normas que regulam o ensino superior em Moçambique, nação situada na Africa Austral. As normas assentes no Decreto 43/2023 de2 de Agosto e Decreto 91/2023 de 29 de Dezembro, visam fortalecer os mecanismos de fiscalização e garantia de qualidade. A escolha do tema constitui preocupação no autor, no que toca ao estudo sobre o percurso das instituições de ensino superior na província de Niassa. Observar as partes dos instrumentos, como desafios para as Unidades Orgânicas existentes na província. As reformas trazidas, se observadas, por um lado serão benéficas para o desenvolvimento do subsistemado ensino superior e por outro lado, asreformas irão obrigar as instituições de ensino superior adescontinuar algum curso ou programa por falta de requisitos. Ainda na óptica do autor, as exigências formuladas visam trazer credibilidade das universidades no que diz respeito aos seus princípios que prezam sobre o ensino, pesquiza, extensão, incubação tecnológica, internacionalização e outros padrões para sua consolidação. O artigo tem como objectivo geral: Verificar a conformidade do funcionamento da instituição com base nas normas vigentes. Os objectivos específicos visam verificara existência de todos elementosnormativos para o funcionamento pleno das unidades orgânicas da IES existente na província de Niassa. Neste contesto, se espera diante das reformas acelerar a qualidade de ensinonas instituições de ensino superior existentes na Província de Niassa. A fiscalização deve servir como um meio de prevenção de riscos, e sanções prevista sirvam como fundamento para parar com o funcionamento de instituições de ensino superior que, cometem irregularidades. A inspecção deve aplicar a Lei, pós se julga ser inoperante em sancionar as instituições infratoras da Lei. ***** CIWUNGANYO  Aci cibuukuci cikuteenda upaande um usoomi  wa n’ciganicisyo, yibuuku, n’kusaala ya kuloleela midingo jiine jaakwe já jikuloleela n’nyikoola yeekuluungwa m’Mosambiki, cilaambo ca cidi kwivaanda kwa n’cigoombo ca África. Midingo já jidi um ulamusi 43/2023 wa 2 mweesi wa Agostu ni ulamusi 91/2023 wa 29 wa mweesi wa Deseemba, wu kupeleka matala ga  ulonda pa kusaka cipatikane citupyo. Kusagula kwa awu n’tengaawu wu kuoneka yisawusyo ya va kuleembava, pa kujaaga matala ga ga-kujigala yikoola yeekuluungwa  n’cigoombo ca ku-Nyassa. Kuloleela n’tupaande, m’pela yidimbi-dimbi n’nyijiiji kapena yikoola yeekuluungwa ya yidi ku-Niassa. Ya yicenjileeyo, naaga kuyilolecesya, m’paka yipelece cikamucisyo n’nyikoola yeekuluungwa, naambo paane paakwe, ci yiteendekaasye kuva laasima yikoola yeekulungwa yine yakwe yikajeendelecela kuluso sine syaakwe digoongo dya kusova yisuuso. Pa kulola kwa va kuleembaava, malamusi ga nyuuwaniga gakusaka kujigadila cikulupi n’nyikoola yeekuluungwayi pakujaaga m’myaambo já jikuloleela m’masoomo-mo, kusosa-sosa,cituuwo, ku wukamicisya m’ma Tekenolojia, kutaandicila m’paka yilaambo yiine ni yipiimo yine yakwe pakuti yikamulane. Aci cibuukuci cikweete cidiimbi- cekuluungwa: Kupima ya yikuti kuseveesa yikoola yeekuluungwayo pa kukuuya midingo. Yidimbi-dimbi yamwana ni yidi ya kuloleela anaaga  yipadi yoose ya yikusacikwa pakuti yikoola yeekuluungwa yiveeje ya kuseveesa mwa n’tendeele ku-Nyassa. Pelepo, yikudindidwa kwa yiciimdu ya yikudindidwa kwa yiciimdo ya yicenjileeyo, kuutusya wusoomi wambone wa yikusacikwa n’nyikoola yeekuluungwa ku-Nyassa. Ulonda uveeje wa kusosegwa pa kuyikaanya yiciindu yakana maate, ni, ukayidi uveeje wa kusosegwa pa kuyiciga yikoola yeekuluungwa ya yikuleka kukuuya midingo. N’kutula wa ulonda uveeje wa kupikunicisya ulamusi, n’taande yikupiikanika kuti ukuteenda uleesi pa kupeleka ukayidi n’nyituwo ya ngayikuuya  ulamusi

    Fatores que estão na base da falta de qualidade de ensino no subsistema do Ensino Primário: estudo de caso Complexo Escolar 4 de Julho Aeroporto/ Lunda Norte: Makambo oyo ezali na nsé ya bozangi ya lolenge ya mateya na sous-système ya Éducation Primaire : étude de cas ya Complexe scolaire 4 de Julho Aéroport/Lunda Norte

    No full text
    O presente trabalho buscou investigar os fatores que estão na base da falta de qualidade de ensino no subsistema do Ensino Primário: estudo de caso Complexo Escolar 4 de Julho Aeroporto/ Lunda Norte. Tendo como questão de base: quais são os fatores que influenciam a fraca qualidade no Ensino Primário no caso do Complexo Escolar 4 de Julho Aeroporto? Daí que se determinou como objetivo geral: caracterizar os fatores que estão na base da falta de qualidade de ensino no subsistema do Ensino Primário. O estudo segue o paradigma quantitativo e tem a Estatística Descritiva como método de tratamento de dados de campo. Ao passo que o inquérito serviu como instrumento de recolha de dados. Aplicou-se o inquérito a oito professores e dois membros da direção da escola para a recolha de dados. A partir da experiência como professora e como investigadora, fez-se a observação das condições da escola e permitiu a caracterização dos principais fatores que condicionam a qualidade, tais como: falta da especialização dos professores nas disciplinas que lecionam e em Ensino Primário, monodocência, sobrelotação de alunos por turma, falta de acompanhamento dos pais e encarregados da educação no processo de ensino-aprendizagem dos educandos. Como principais conclusões destacam-se que é preciso que se aumentem as salas de aulas a fim de acrescentar mais tempo letivo porque o processo de desdobramento dificulta o cumprimento das atividades por parte dos professores, faltam condições nas escolas que aumentem a aprendizagem dos alunos, por exemplo, bibliotecas escolares e merenda. **** NA MOKUSE (lingala) Boyekoli oyo elukaki koluka koyeba makambo oyo ezali na nsé ya bozangi ya lolenge ya mateya na sous-système ya Éducation primaire : étude de cas ya Complexe scolaire 4 de Julho, Aeroporto/Lunda Norte. Kozala na motuna ya moboko : nini ezali makambo oyo ezali na bopusi na lolenge ya mabe ya Eteyelo ya Ebandeli na likambo ya Complexe Ecole 4 de Julho Aeroporto? Na yango, mokano ya monene ezuami : ko caractériser ba facteurs oyo ezali sous-jacente ya manque ya enseignement ya qualité na sous-système ya Éducation de base. Boyekoli elandi paradigme quantitatif pe esaleli Statistiques Déscriptives lokola méthode ya traitement ya ba données ya terrain. Alors que anketi esalaki lokola esaleli ya bosangisi ba données. Ankɛtɛ yango esalemaki na balakisi 08 mpe bato 02 ya bakambi ya biteyelo mpo na kosangisa makambo. Na kotalela mayele na ngai lokola molakisi mpe moluki, namonaki makambo ya eteyelo mpe napesaki ngai nzela ya ko caractériser ba facteurs principals oyo ezali ko affecter qualité, lokola : manque ya spécialisation ya balakisi na ba matières oyo bateyaka mpe na éducation primaire, mateya ya molakisi moko, surreplance ya ba élèves par classe, manque ya suivi ya ba parents na ba gardiens na processus ya enseignement-apprentissage ya ba élèves. Bosukisi ya minene ezali na ntina ya komatisaka motango ya bakelasi mpo na kobakisa tango ya mateya mingi mpo ete mosala ya botiami na mosala esalaka ete balakisi ezala mpasi mpo na kosala misala na bango, mpe biteyelo ezali na makambo te mpo na kobakisa boyekoli ya banakelasi, ndakisa, bozangi ya bibliothèques ya biteyelo mpe bilei ya kelasi

    579

    full texts

    1,125

    metadata records
    Updated in last 30 days.
    Revistas da Unilab (Univ. da Integração Internacional da Lusofonia Afro-Brasileira)
    Access Repository Dashboard
    Do you manage Open Research Online? Become a CORE Member to access insider analytics, issue reports and manage access to outputs from your repository in the CORE Repository Dashboard! 👇