Revistas da Unilab (Univ. da Integração Internacional da Lusofonia Afro-Brasileira)
Not a member yet
    1125 research outputs found

    Ewì Alohùn Nínú Lítírés̩ò̩ Àpilè̩ko̩ Yorùbá: Ìwé Eré-onítàn O̩mo̩ Aláte̩ Ìlè̩kè̩ tí Láwuyì Ògúnniran ko̩ bí Àpe̩e̩re̩: Poemas na literatura iorubá: A história do filho do profeta, de Lawuyì Ógúnnirán

    Full text link
    ÀS̩AMÒ̩ (Yoruba) Àwo̩n onímò̩ tíó̩rì ìje̩mó̩pò̩ às̩à ti fidì rè̩ múlè̩ pé kò sí àwùjo̩ tí kò ní às̩à tirè̩, bé̩è̩ ni káríayé bí as̩o̩ onís̩úgà ni ìs̩è̩s̩e jé̩ sí gbogbo orílè̩-èdè ayé. Kò síbi tí a kì í gbé dáná alé̩, o̩bè̩ lè dùn jura wo̩n lo̩.  Inú às̩à lá sì ti fa lítírés̩ò̩ jade fún àǹfààní àti ìgbádùn àwo̩n ènìyàn àwùjo̩ tí ó ni às̩à náà.  Ò̩nà méjì à ń gbà gbé lítírés̩ò̩ jade lágbàáyé, a lè so̩ lé̩nu, kí ó jé̩ eré e̩nu, ó sì lè jé̩ àpilè̩ko̩. Èyí tí a ń so̩ lé̩nu ló wó̩pò̩ jù ní ilè̩ Afirika.  Òun ni à pè ní lítírés̩ò̩ alohùn lóde-òní dípò lítírés̩ò̩ àte̩nudé̩nu tàbí àbáláyé tí à ń pè é té̩lè̩. Púpò̩ nínú àwo̩n onímò̩ is̩é̩ lámèyító̩ ló ti wo ipò àti ipa tí ewì alohùn Yorùbá ń kó nínú lítírés̩o̩ àpilè̩ko̩ Yorùbá àti ìje̩yo̩ rè̩ nínú ìwé èré-onítàn s̩ùgbó̩n abala tí a wò ló jé̩ tuntun èyí ni ìs̩àmúlò ewì alohùn nínú ìwé eré-onítàn aje̩mó̩ ìmò̩-ìtàn O̩mo̩ Aláte̩ Ìlè̩kè̩ tí Láwuyì Ògúnniran ko̩. Àwo̩n onís̩é̩ lámèyító̩ kò tíì fi bé̩è̩ wo ipò àti ipa tí ewì alohùn kó nínú eré yìí bí wó̩n s̩e wo àwo̩n ìwé eré-onítàn aje̩mó̩ ìmò̩-ìtàn yòókù. Nítorí náà, èròǹgbà wa ni láti s̩e àgbéyè̩wò ìs̩àmúlò ewì alohùn nínú eré náà. O̩gbó̩n ìs̩èwádìí tí a lò ni agbàlàyé (Descriptive method), a dìídì yan ìwé eré-onítàn O̩mo̩ Aláte̩ Ìlè̩kè̩ láàárín àwo̩n eré aje̩mó̩ ìmò̩-ìtàn nítórí pé is̩é̩ lámèyító̩ kò tíí pò̩ lórí rè̩. A s̩e àmúlò tíó̩rì aje̩mó̩ ìmò̩-ìtàn nítorí ìtàn ìs̩è̩dálè̩ ilè̩ Yorùbá tó kún fún ìjìnlè̩ ohùn e̩nu Yorùbá ni, ó sì dálé ìtàn ogun. Àbò̩ ìwádìí fihàn pé bí àmù omi ńlá ni ewì alohùn Yorùbá jé̩ fún eré-onítàn àpilè̩ko̩, èyí tí àwo̩n òǹkò̩wé òde-òní ti ń bù mu, tí wó̩n sì ń bù wè̩ bí ó tilè̩ jé̩ pé wó̩n ń dárà sí is̩àmúlò rè̩; a rí ìje̩yo̩ òwe, oríkì, àwís̩e̩ bí o̩fò̩, àásán, ayájó̩, èpè àti orin nínú ìgbékalè̩ àti àhunpò̩ ìtàn, ibùdó eré, ìfìwàwè̩dá, ìlò èdè, kókó-ò̩rò̩. Ìkádìí rè̩ ni pé òpìtàn pàtàkì ni Alàgbà Láwuyì Ogunniran, akéwì ìsè̩ǹbáyé tó jinlè̩ nínú ewì alohùn Yorùbá ni, ó sì fi ìwé O̩mo̩ Aláte̩ Ìlè̩kè̩ pàrokò sí ìran Yorùbá pé kí wó̩n jáwó̩ lápò̩n tí ò yò̩, kí wó̩n gbómi ilá kaná, kí wó̩n wà ní ìré̩pò̩ láìjà mó̩, kí ò̩mo̩ aláte̩ ìlè̩kè̩ má bàá do̩mo̩ aláte̩ ò̩rúnlá àti pé kí ewì àlohùn Yorùbá ó wà títí láé fún ìran tó ń bò̩ lé̩yìn.   **** Os estudiosos da linguística confirmaram que não existe sociedade que não tenha sua própria língua e, no mundo, como língua comum, ela é usada por todas as nações. Não há lugar onde não vivamos e possamos apreciá-la. E a literatura tem sido produzida a partir da língua para o benefício e o prazer das pessoas da sociedade que a possui. Há duas maneiras pelas quais a literatura é transmitida ao mundo: ela pode ser falada, como forma de entretenimento, e pode ser usada como ferramenta. A língua falada é a mais comum na África. É chamada de literatura oral moderna, em vez de literatura oral ou literária, como era chamada anteriormente. Muitos estudiosos examinaram o papel e o lugar da poesia oral iorubá na tradição literária iorubá e seu uso na ficção histórica, mas o aspecto que estamos examinando é novo, ou seja, o uso da poesia oral no romance de ficção histórica Omo Aláte Îleke, escrito por Lawuyì Ògúnnirán. O papel e a função da poética nesta peça não foram examinados por estudiosos como em outros dramas históricos. Portanto, nosso objetivo é examinar o uso da poética na peça. O método de pesquisa utilizado é descritivo, e escolhemos especificamente a peça Omo Aláte Îleke entre os dramas históricos porque não há muitos trabalhos acadêmicos sobre ela. A teoria da ficção histórica é usada porque a história da nação iorubá é repleta da profundidade da língua iorubá e é baseada na história da guerra. Pesquisas mostram que a poesia iorubá é como um grande reservatório para o drama histórico, que os escritores modernos têm bebido e ainda bebem, embora sejam bons em seu uso; vemos o uso de provérbios, poesia, provérbios como ofo, àasan, ayájo, épe e canção no desenvolvimento e desenvolvimento da história, o cenário do drama, a criatividade, o uso da linguagem, o tema. Sua conclusão é que o Ancião Lawuyì Ogunniran é um grande historiador, um poeta profundamente enraizado na poesia iorubá, e ele escreveu o livro O̩mo̩ Aláte̩ Île̩ke̩, no qual ele exortava a geração iorubá a se libertar do mal, a se libertar do mal, a se libertar do mal, para que o mal do passado não seja esquecido e que a poesia iorubá permaneça para sempre para as gerações futuras

    Òwe Yorùbá Gẹ́gẹ́ bí Àpẹẹrẹ Ọnà-èdè Alátinúdá Ajẹmẹ́wà: Kò Gbọdọ̀ Kú: Provérbios yorubás como exemplo de linguagem criativa: ela não deve morrer

    Full text link
    ÀṢAMỌ̀ Iṣẹ́ àpilẹ̀kọ yìí ṣe àgbéyẹ̀wò òwe èdè Yorùbá tó jẹ mọ́ ẹ̀kọ́ ilé àti ìpẹ̀tùsááwọ̀ láwùjọ Yorùbá. Yorùbá gbà pé òwe jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọnà-èdè ajẹmẹ́wà alátinúdá èyí tó jẹ́ orísun ìmọ̀ ẹ̀kọ́-ilé àti ìpẹ̀tùsááwọ̀. Èdè Yorùbá jẹ́ ọ̀kan lára èdè abínibí ní Nàìjíríà tí ó ní olùsọ mílíọ̀nù ọgbọ̀n. Wọ́n tún ń sọ ọ́ ní Benin, Togo, Siera-Leone, Brazil, Cuba, Trinidad àti Tobago, Amẹ́ríkà abbl. Ó jẹ́ èdè olóhùn tó ní ìhun Olùwà-Ọ̀rọ̀-ìṣe-Àbọ̀ (Subject-Verb-Object). Ó jẹ́ ẹ̀yà ìpín èdè Benue Congo titun. Àmúlò òwe láwùjọ lóde òní kò dàbí ti àtijọ́ mọ́. Àwọn àgbàlagbà tí wọ́n máa ń pa òwe nípasẹ̀ ìrírí wọn ti ń dínkù. Àwa ọ̀dọ́ tí a sì wà kò ní ìrírí tó jinlẹ̀ tí ó sì lè mú kí a máa pa òwe láwùjọ. Ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́ tí a fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò nípa ìmọ̀ wọn nínú òwe pípa ní pàtàkì èyí tó jẹ mọ́ ẹ̀kọ́-ilé àti ìpẹ̀tùsááwọ̀ ni wọ́n kùnà. Ìpèníjà lèyí, tó ń wá àmójútó ní kíákíá. Ìdí nìyí tí a fi dáwọ́ lé iṣẹ́ ìwádìí yìí, kí á lè wá ojútùú sí ìṣòro yìí, kí àwọn òwe wa má ba kú. Tíọ́rì ìbára-ẹni-gbé-pọ̀-láwùjọ àti ti ìpẹ̀tùsááwọ̀ ni a mú lò nínú iṣẹ́ yìí. Ọgbọ́n ìwádìí tí a mú lò fún àkójọpọ̀ èdè fáyẹ̀wò ni títọ àwọn olùsọ èdè yìí tí ọjọ́ orí wọn bẹ̀rẹ̀ láti àádọ́ta sí ọgọ́rin lọ fún oríṣiríṣi òwe àti àmúlò wọn. A wo àwọn ìwé àti iṣẹ́ àpilẹ̀kọ lórí òwe wò. A wo orí ẹ̀rọ ayélujára bákan náà. Àbájáde iṣẹ́ yìí jẹ́ ká ní ìmọ̀ nípa oríṣiríṣi àwọn òwe Yorùbá bó ti ṣe kan ẹ̀kọ́-ilé àti ìpẹ̀tùsááwọ̀. Ó wúlò fún kíkọ́ ọmọ ní ìwà ọmọlúwàbí èyí tó máa ń ṣe ìgbélárugẹ àṣà, ìṣe àti ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá, tó sì ń yọrí sí ìbára-ẹni-gbé-pọ̀ alálàáfíà. Nínú iṣẹ́ yìí, a wo oríkì, ẹ̀dá káríayé àti ìwúlò òwe ní pàtàkì òwe fún ẹ̀kọ́-ilé àti ti ìpẹ̀tùsááwọ̀. A wo “Yorùbá” gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ àti àwọn ẹ̀yà kan. Òwe mú kí àyípadà dé bá àwùjọ sí rere. Ipa tó ń kó nínú ìpẹ̀tùsááwọ̀ láwùjọ kò kéré. Àwọn ìwúlò wọ̀nyí ni òwe kò fi gbọ́dọ̀ kú. ***** Este artigo examina os provérbios iorubás relacionados à educação doméstica e à reconciliação na sociedade iorubá. Os iorubás acreditam que os provérbios são uma das artes da linguagem criativa, fonte de conhecimento sobre educação doméstica e reconciliação. O iorubá é uma das línguas indígenas da Nigéria, com trinta milhões de falantes. Também é falado no Benim, Togo, Serra Leoa, Brasil, Cuba, Trinidad e Tobago, Estados Unidos, etc. É uma língua tonal com estrutura sujeito-verbo-objeto. É um novo dialeto benue-congo. O uso de provérbios na sociedade atual não é o mesmo do passado. O número de adultos que usam provérbios com base em suas experiências está diminuindo. Nós, jovens, não temos a experiência profunda que nos leva a usar provérbios na sociedade. Muitos jovens que entrevistamos sobre seu conhecimento de provérbios, especialmente aqueles relacionados à educação doméstica e ao perdão, fracassaram. Este é um desafio que precisa de atenção urgente. É por isso que empreendemos este projeto de pesquisa, para encontrar uma solução para este problema, para que nossos provérbios não morram. A teoria da interação social e do perdão foi utilizada neste trabalho. O método de pesquisa utilizado para a coleta de dados foi entrevistar falantes dessa língua, com idades entre cinquenta e oitenta anos, para vários provérbios e seus usos. Analisamos livros e artigos sobre provérbios. Também consultamos a internet. Os resultados deste trabalho nos deram conhecimento sobre vários provérbios iorubás relacionados à educação doméstica e à reconciliação. Eles são úteis para ensinar às crianças boas maneiras que promovem a cultura, os costumes e as crenças iorubás, e levam à coexistência pacífica. Neste trabalho, examinamos a poesia, o mundo e os usos dos provérbios, especialmente aqueles para a educação doméstica e a reconciliação. O "iorubá" é visto como um meio de comunicação e um meio de comunicação entre certas tribos. Os provérbios trazem mudanças positivas na sociedade. Seu papel na reconciliação social não é pequeno. Esses são os usos que os provérbios não devem ser esquecidos

    Ta Ló Lè Ṣe É?

    Full text link
    Ta Ló Lè Ṣe É

    Nzema edwɛhanlɛ bie mɔ mɔɔ sonlabaka nvɛyeba ‘nye’ finde nu la nvedenvedenu: A study of figurative expressions related to nye ‘EYE(s)’ in Nzema

    No full text
    SINLIPƐLƐ Nzema boka Kwa aneɛ abusua ne anwo. Bɛka ye wɔ Gana Sɛnzɛndɔleɛ wɔ adɔleɛ maanzinli ne anu. Nzema aneɛ ne gua ye ekpunli nnu. Bɛmɛ a le Dwᴐmᴐlᴐ, Ɛlεmgbεlε, Adwɔmɔlɔ, Egila yɛɛ Ɛvaloε (Annan, 1980; Kwaw, 2008). Nuhua ne mɔɔ bɛlie bɛdo nu na bɛsukoa eza bɛkɛlɛ ɔbɔ ye mɔlɛbɛbo sukulu kɔdwu sukunsa la a le Dwᴐmᴐlᴐ ɛdeɛ ne. Menli ne nee aneɛ ne kɔsɔɔti bɛfɛlɛ bɛ Nzema (Kwesi, 1992). Kuane ne mɔɔ nea maa bɛtia menli nee azua la bu mgbonda kɛ, wɔ ɛvolɛ 2021 ne anu ɛdianlɛ ɛdeɛ ne ɛnee Nzemama dodo le 342 090. Nwomama ɛli gyima dɔɔnwo ɛmaa yela ali kɛ aneɛ aneɛ dɔɔnwo gyinla sonlabaka nvɛyeba ngakyile ne mɔ azo ka edwɛkɛ bie mɔ. Nzema noko fa sonlabaka nvɛyeba ne mɔ nwo edwɛkɛ ngakyile dɔɔnwo mɔɔ ‘ɛnyelɛ’ ɛmkpa nu a. Noko akee gyima mɔɔ fale ‘ɛnyelɛ’ nwo la anzo wɔ Nzema nu. Gyima ɛhye bodane a le kɛ ɔfedevede kɛ Nzema si fa ‘ɛnyelɛ’di gyima wɔ edwɛkɛhanlɛ bie mɔ anu la anu. Yɛnyianle edwɛkɛ mɔɔ yɛvale yɛlile gyima ɛhye la yɛvile sukoavoma mɔɔ wɔ Adwumako Sukunsa ne anu la anu mɔtwɛ ɛkɛ. Kɛmɔ yɛle Nzemama la ati, yɛdayɛ noko yɛvale edwɛkɛ ne bie yɛbokale nwo. Akee yɛluale bɛnloanu edwɛmiza zo yɛ nee mgbanyima nwiɔ mɔɔ ɛbe aneɛ ne anu la lile adwelie vale edwɛkɛ mɔɔ yɛnyianle ye la anwo, na bɛvoale zo kɛ ɔdi munli. Nvedenvedenu ne gyi aneɛnu ninyɛne mɔɔ findevinde edwɛkɛhanlɛ mɔɔ bɛfa ‘ɛnyelɛ’ bɛdi gyima wɔ nu la azo titili. Gyima ɛhye guabelɛ ne maa ɔda ali kɛ Nzema ɛnva ‘ɛnyelɛ’ ɛnnea debie angome; emomu, eza bɛfa bɛdi gyima wɔ edwɛkɛhanlɛ nu bɛfa bɛkile abotane, anyelazo, debie boɛ ɛyɛlɛ, akɛnrasesebɛ nee mɔɔ bokɛboka nwo la

    Orin Kúlúńbú: Ọnà Ìfiniṣẹ̀fẹ̀ àti Ìjánu Àwùjọ ní Ìlú Ọjà-Ọ̀dàn Yewa

    Full text link
    Ṣaájú kí àwọn Òyìnbó tó dé ilẹ̀ Adúláwọ̀ pàápàá ilẹ̀ Yorùbá, onírúurú isẹ́-ọnà ajẹmọ́-ìpohùn ni ó wà ní agbègbè kọ̀ọ̀kan tí wọ́n sì máa ń wà bí ohun ìdámọ̀ fún agbègbè tí wọ́n bá ti ń lò wọ́n. Ọ̀kan nínú àwọn iṣẹ́-ọnà ajemọ́-ìpohùn yìí ni orin jẹ́ láàárín àwọn ẹ̀yà Yorùbá, ó sì wà fún ìnàjú, ìdánilárayá àti ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. Èyí ni ó máa ń mú kí àwùjọ àwọn Yorùbá ní ìfẹ́ sí orin kíkọ níbikíbi, nígbàkúùgbà àti lórí ohunkóhun. Ọ̀kan nínú àwọn orin ìbílẹ̀ Yorùbá tí ó gbajúmọ̀ láàárín àwọn ènìyàn ìlú Ọ̀jà-Ọ̀dàn ni orin Kúlúḿbú tí ó jẹ orin ajemọ́-eré-oníṣe, tí ó sì tún jẹ mọ́ ìfiniṣẹ̀fẹ̀. Ìlépa iṣẹ́ yìí ni láti ṣe àfihàn orin Kúlúńbú ní ìlú Ọjà-Ọ̀dàn gẹ́gẹ́ bí ọnà ìṣèré ìpohùn Yorùbá, kí a ṣe ìtúpalẹ̀ àwọn àkóónú rẹ̀, kí á sì tọ́ka sí àwọn irúfẹ́ ọnà ìfiniṣẹ̀fẹ̀ inú orin yìí pẹ̀lú ọ̀nà tí ó ń gbà fọ àwùjọ mọ́. A ṣe àkójọ àwọn orin Kúlúḿbú tí a lò ní ìlú Ọ̀jà-Ọ̀dàn ní agbègbè Yewa ní ìpínlè Ogun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A ṣe òfintótó ìṣèré orin yìí, a sì kópa nínú ìgbékalẹ̀ orin náà. A ṣe àfàyọ àwọn àbùdá eré-oníṣe àti ọnà ìfiniṣẹ̀fẹ̀ tí ó ń jẹ yọ nínú àgbékalẹ̀ orin Kúlúḿbú àti ipa rẹ̀ lórí àwọn ènìyàn àwùjọ. Iṣẹ́ yìí ṣe àfihàn àwọn ẹ̀yà Yorùbá Yewa gẹ́gẹ́ bí alárògún àti oníṣẹ́-ọnà ajẹmọ́-ìpohùn, ó sì tọ́ka sí bí wọ́n ṣe ń lo orin Kúlúńbú fún ìtọ́sọ́nà ètò ìgbé-ayé wọn, ọ̀nà  ìjánu àwùjọ àti fún ìdàgbàsókè àwùjọ wọn. Iṣẹ́ yìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé, iṣẹ́-ọnà láàárín àwọn Yorùbá ń dàgbà sókè lójoojúmọ́ àti pé ìyípadà ọ̀tun ni orin Kúlúḿbú ń mú bá agbègbè tí ó ti ń wáyé. Èyí ni ó sì yẹ kí ó jẹ́ àwòkọ́ṣe fún àwọn oníṣé-ọnà káàkiri ilẹ̀ Yorùbá àti gbogbo àgbáyé

    PSICOLOGIA AMBIENTAL PARA O ESTUDO DO AMBIENTE

    Full text link
    O presente artigo trata acerca da conceituação da Psicologia Ambiental, área da Psicologia que investiga as reciprocidades entre pessoa e ambiente, no entendimento que a pessoa age sobre o ambiente, influencia-no, reestrutura-no, ao passo que o ambiente também a influencia, possui um efeito sobre a mesma, pode modificar o comportamento ou as condutas. Essa compreensão dá ênfase ao fato de que a Psicologia Ambiental não estuda o ambiente como foco único e particular ou o indivíduo restrito aos seus processos mentais. Mas, ambiente e indivíduo são analisados no nível das inter-relações entre eles, em suas dinâmicas específicas. Para a análise conceitual, coloca-se a concepção histórico-cultural da relação pessoa-ambiente. Nessa concepção histórico-cultural da relação pessoa-ambiente leva-se em conta que este ambiente, construído socialmente, denota uma dimensão de uma subjetividade que se faz na relação com o mundo, representando o potencial de intervenção das pessoas para a transformação da realidade, ao mesmo tempo em que as pessoas transformam a si mesmas. Para o delineamento teórico, apresenta-se as categorias da Psicologia Ambiental, tais como Identidade de Lugar, Simbolismo do espaço e Apropriação do espaço. Ao se vincular a relação de em estar subjetivo e Psicologia Ambiental, compreende-se que conviver nos ambientes perpassa pela humanização dos espaços, na medida em que os ambientes naturais ou construídos fazem parte dos processos de construção histórico-cultural das sociedades, imprimindo naqueles os aspectos subjetivos e afetivos das relações humano-ambientais

    MÃOS EM PUNHO:: POÉTICA DA REVOLUÇÃO EM JOSÉ EDUARDO AGUALUSA, A VEZ DA CRÔNICA

    Full text link
    O presente artigo tem o objetivo de analisar o gênero crônica na produção literária do escritor José Eduardo Agualusa, com destaque para treze delas publicadas no jornal português Visão, entre 2019 e 2020. Agualusa reforça, em Os Vivos e os Outros, que a palavra é o motor da história. “No princípio era o Verbo, e o Verbo estava voltado para Deus, e o Verbo era Deus” (Jo 1,1). O romance trata do fim do mundo, mas têm um lado redentor: o de que é possível recomeçar o mundo pela palavra. A proposta da investigação foi identificar temas recorrentes, como guerras de independência, pós-colonialismo, democracias em xeque, corrupção, personagens colhidos da História ou da memória afetiva do autor, presentes em outras produções (romances, contos, poesia e literatura infantil). O estudo demonstrou que a presença de elementos comuns em gêneros literários que transitam entre si sugere um estilo, ora intitulado “poética da revolução”. Não se trata de algo exclusivo de Agualusa, longe disso, é uma característica bem marcada de outros escritores e escritoras de literatura africana. Acredita-se, assim, contribuir com novas perspectivas para os Estudos Literários, especialmente relacionados a estudos pós-coloniais. Na fundamentação teórica, apresentam-se algumas hipóteses para as questões levantadas. São elencados os principais temas tratados pelo escritor angolano em treze crônicas publicadas entre 2019 e 2020, que vão da resistência ao animismo, passando pela poesia do cotidiano

    EXPERIÊNCIAS COMO BOLSISTA DO NUCLI NA UNILAB: DESAFIOS E AVANÇOS NO ENSINO-APRENDIZAGEM DA LINGUA FRANCESA

    Full text link
    O ensino da língua francesa na Universidade da Integração Internacional da Lusofonia Afro-Brasileira (UNILAB), por meio do Núcleo de Línguas (NUCLI), constitui um espaço estratégico para o desenvolvimento cultural, acadêmico e profissional dos estudantes e da comunidade externa. Este estudo tem como objetivo analisar as práticas pedagógicas e a experiência formativa do bolsista de francês, destacando os avanços e os desafios no processo de ensino e aprendizagem. O trabalho é de natureza qualitativa, fundamenta-se em um estudo de caso e em revisão bibliográfica, com aplicação de metodologias expositiva, explicativa e prática nas turmas do curso de francês, iniciante e avançado, na Unidade Acadêmica dos Palmares. Os resultados evidenciam progressos significativos na competência linguística e intercultural dos estudantes, fruto da integração entre teoria e prática e do uso de recursos tecnológicos e metodologias contextualizadas. Entretanto, observam-se desafios institucionais, como a carência de políticas de incentivo, materiais didáticos e eventos formativos que ampliem as oportunidades de prática comunicativa. Conclui-se que o fortalecimento do NUCLI depende da continuidade do investimento em formação docente, intercâmbio cultural e ações que promovam uma aprendizagem significativa e intercultural

    A Relação entre procastinação e sucesso académico: Reflexão sobre R = U/I dos Estudantes na Leitura, Gestão do Tempo como Factor de Câbula Resultante dos Desafios dos Docentes Iniciantes no Ensino Superior na Avaliação Formativa em Moçambique: The Relationship between Procrastination and Academic Success: Reflection on R = U/I of Students in Reading, Time Management as a Factor of Cheating Resulting from the Challenges of Novice Teachers in Higher Education in Formative Assessment in Mozambique

    Full text link
    Este  artigo científico intitula-se R = U/I dos  Estudantes na Procastinação de leitura como Factor de Câbula Resultante dos Desafios dos Docentes Iniciantes no Ensino Superior na Avaliação Formativa em Moçambique e seu objetivo é avaliar os desafios dos docentes iniciantes no ensino superior,fazendo ponte na busca de aspectos relacionados a pesquisa reflete nos estudantes na resistecnia de viciar as cábulas,  no referecnial teóricos que abordam a temática, além da contribuição de outras pesquisas realizadas sobre avaliação formativa para docentes iniciantes do ensino superior destacando a importância para se efetivar a promoção, valorização dos estudantes e a correção das possíveis distorções observadas durante o percurso de produção. O trabalho baseia numa pesquisa documental por meio de uma revisão de literatura. Esta pesquisa contribui para reflexão sobre a avaliação formativa no processo ensino e aprendizagem, além ainda de ser um dos referenciais para outros pesquisadores que desejam dar continuidade na carreira. *****  This scientfic article is entitled, challenges of novice teachers in higher education regarding formative assessmenr in Mozambique , and its objective is to evaluate the challenges faced by novice teachers in higher education , bridging aspects  realted to research reflected in the theoretical refrences that address the theme, in addition to the the contribution of other studies conducted on formative assessment for novice higher education teachers, highlighting itis inportance in promoting , valuing studentes , and correcting possible distortions observed during the production process. The work is based on documentary research through a literature review. This research contributes to the reflection on foramtive assessment in the teaching and learning process, as well as serving aas a refrence for other researchers who wish to continue in their careers

    Envolvimento dos Pais e Encarregados da Educação na melhoria do Processo de Ensino e Aprendizagem de Leitura dos Alunos da 3ª classe na Escola Primária completa do Vaz - Moçambique (2021-2022)

    Full text link
    This article aims to analyze the involvement of parents and guardians in improving the teaching and learning process of reading for 3rd grade students at EPC do Vaz-Beira. The problem with this research is the weak involvement of parents and guardians at school. To materialize this research, it was based on the following methodologies: descriptive qualitative research, the bibliographic method, the inductive method, using observation and interview techniques. This research has a population of 3380, with 780 students. 2600 parents in charge of education; with a sample of 90: 45 students and 45 parents in charge of education. The main results of this investigation reveal that the causes of weak involvement of parents and guardians have been the lack of time due to occupations in the service, some parents do not have reading skills and some have a tutor who replaces their role, because of this, the level of involvement of parents and guardians is so low. The role of parents and guardians has been to help teachers understand their students\u27 learning problems in accordance with the statements of parents and guardians.A família é o núcleo central de todo o processo educacional, por ser a unidade fundamental da sociedade e o lugar onde o aluno passa a maior parte do seu tempo durante todo o processo de sua formação acadêmica e social. A família deve ser convidada a contribuir de maneira mútua na criação de um novo indivíduo para o mundo. O presente artigo visa analisar o envolvimento dos pais e encarregados da educação na melhoria do processo de ensino e aprendizagem de leitura dos alunos da 3ª Classe na Escola Primária completa do Vaz-Moçambique,. O problema desta pesquisa é o fraco envolvimento dos pais e encarregados de educação na escola. Para materialização desta pesquisa foi com base das seguintes metodologias: a pesquisa qualitativa descritiva, o método bibliográfico, o método indutivo, com recurso as técnicas de observação directa e entrevista semi-estruturada. Essa pesquisa tem como amostra de 90, sendo: 45 alunos e 45 pais encarregados de educação com base no procedimento de amostragem não probabilística na modalidade de intencionalidade ou conveniência. Os principais resultados desta investigação revelam que, as causas de fraco envolvimento dos pais e encarregados tem sido a falta de tempo. Muitos pais não dominam a leitura e alguns contam com um explicador que desempenha o seu papel. Por isso, o grau de envolvimento dos pais e responsáveis pela educação é tão baixo. A função dos pais e responsáveis tem sido auxiliar os docentes a compreender as dificuldades de aprendizado de seus alunos, conforme suas declarações

    579

    full texts

    1,125

    metadata records
    Updated in last 30 days.
    Revistas da Unilab (Univ. da Integração Internacional da Lusofonia Afro-Brasileira)
    Access Repository Dashboard
    Do you manage Open Research Online? Become a CORE Member to access insider analytics, issue reports and manage access to outputs from your repository in the CORE Repository Dashboard! 👇